Luk 22:64 YCE

64 Nigbati nwọn si dì i loju, nwọn lù u niwaju, nwọn mbi i pe, Sọtẹlẹ, tani lù ọ nì?

Ka pipe ipin Luk 22

Wo Luk 22:64 ni o tọ