15 Ati Herodu pẹlu: o sá rán a pada tọ̀ wa wá; si kiyesi i, ohun kan ti o yẹ si ikú a ko ṣe si i ti ọwọ́ rẹ̀ wá.
Ka pipe ipin Luk 23
Wo Luk 23:15 ni o tọ