Luk 23:55 YCE

55 Ati awọn obinrin, ti nwọn bá a ti Galili wá, ti nwọn si tẹle, nwọn kiyesi ibojì na, ati bi a ti tẹ́ okú rẹ̀ si.

Ka pipe ipin Luk 23

Wo Luk 23:55 ni o tọ