Luk 24:25 YCE

25 O si wi fun wọn pe, Ẹnyin ti oyé ko yé, ti o si yigbì li àiya lati gbà gbogbo eyi ti awọn woli ti wi gbọ́:

Ka pipe ipin Luk 24

Wo Luk 24:25 ni o tọ