Luk 24:38 YCE

38 O si wi fun wọn pe, Ẽṣe ti ara nyin kò lelẹ̀? ẽsitiṣe ti ìrokuro fi nsọ ninu ọkàn nyin?

Ka pipe ipin Luk 24

Wo Luk 24:38 ni o tọ