Luk 3:15 YCE

15 Bi awọn enia si ti nreti, ti gbogbo wọn si nrò ninu ara wọn nitori Johanu, bi on ni Kristi bi on kọ́;

Ka pipe ipin Luk 3

Wo Luk 3:15 ni o tọ