Luk 4:34 YCE

34 O ni, Jọwọ wa jẹ; kini ṣe tawa tirẹ, Jesu ara Nasareti? iwọ wá lati pa wa run? emi mọ̀ ẹniti iwọ iṣe; Ẹni Mimọ́ Ọlọrun.

Ka pipe ipin Luk 4

Wo Luk 4:34 ni o tọ