Luk 5:22 YCE

22 Ṣugbọn nigbati Jesu mọ̀ ìro inu wọn, o dahùn o si wi fun wọn pe, Kili ẹnyin nrò ninu ọkàn nyin?

Ka pipe ipin Luk 5

Wo Luk 5:22 ni o tọ