Luk 5:27 YCE

27 Lẹhin nkan wọnyi o jade lọ, o si ri agbowode kan ti a npè ni Lefi, o joko ni bode: o si wi fun u pe, Mã tọ̀ mi lẹhin.

Ka pipe ipin Luk 5

Wo Luk 5:27 ni o tọ