Luk 8:1 YCE

1 O si ṣe lẹhinna, ti o nlà gbogbo ilu ati iletò lọ, o nwasu, o nrò ìhin ayọ̀ ijọba Ọlọrun: awọn mejila si mbẹ lọdọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Luk 8

Wo Luk 8:1 ni o tọ