Luk 8:12 YCE

12 Awọn ti ẹba ọ̀na li awọn ti o gbọ́; nigbana li Èṣu wá o si mu ọ̀rọ na kuro li ọkàn wọn, ki nwọn ki o má ba gbagbọ́, ki a ma ṣe gbà wọn là.

Ka pipe ipin Luk 8

Wo Luk 8:12 ni o tọ