Luk 9:28 YCE

28 O si ṣe bi iwọn ijọ kẹjọ lẹhin ọ̀rọ wọnyi, o mu Peteru, ati Johanu, ati Jakọbu, o gùn ori òke lọ lati gbadura.

Ka pipe ipin Luk 9

Wo Luk 9:28 ni o tọ