2 Kíróníkà 1:14 BMY

14 Sólómónì kó kẹ̀kẹ́ àti ẹsin jọ, ó sì ní ẹgbàáje kẹ̀kẹ́ àti ẹgbàafà ẹlẹ́sin, tí ó kó pamọ́ sí ìlú kẹ̀kẹ́ àti pẹ̀lú rẹ̀ ni Jérúsálẹ́mù

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 1

Wo 2 Kíróníkà 1:14 ni o tọ