2 Kíróníkà 1:2 BMY

2 Nígbà náà, Sólómónì bá gbogbo Ísírẹ́lì sọ̀rọ̀ sí àwọn alákóso ẹgbẹgbẹ̀rún àti àwọn alákòóso ọ̀rọ̀rún, sí àwọn adájọ́ àti sí gbogbo àwọn olórí Ísírẹ́lì, àwọn olórí ìdílé

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 1

Wo 2 Kíróníkà 1:2 ni o tọ