2 Kíróníkà 1:9 BMY

9 Nísinsinyìí Olúwa Ọlọ́run, jẹ́ kí ìlérí rẹ sí baba à mi Dáfídì di mímúsẹ, nítorí ìwọ ti fi mí jẹ ọba lóri àwọn ènìyàn tí ó pọ̀ bí erùpẹ̀ ilẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 1

Wo 2 Kíróníkà 1:9 ni o tọ