2 Kíróníkà 10:12 BMY

12 Ní ọjọ́ kẹ̀ta Jéróbóámù àti gbogbo ènìyàn sì padà sí ọ̀dọ̀ Réhóbóámù, gẹ́gẹ́ bí ọba ti sọ, “Ẹ padà wá sọ́dọ̀ mi ní ọjọ́ kẹ̀ta.”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 10

Wo 2 Kíróníkà 10:12 ni o tọ