2 Kíróníkà 10:2 BMY

2 Nígbà tí Jéróbóámù ọmọ Nébátì gbọ́ èyí ó wà ní Éjíbítì, níbi tí ó ti sá kúrò lọ́dọ̀ ọba Sólómónì ó sì padà láti Éjíbítì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 10

Wo 2 Kíróníkà 10:2 ni o tọ