2 Kíróníkà 12:1 BMY

1 Lẹ́yìn ìgbà tí a fi ipò Réhóbóámù gẹ́gẹ́ bí ọba lélẹ̀, tí ó sì ti di alágbára, òun àti gbogbo Ísírẹ́lì, pẹ̀lú rẹ̀ ni wọ́n pa òfin Olúwa tì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 12

Wo 2 Kíróníkà 12:1 ni o tọ