2 Kíróníkà 12:10 BMY

10 Bẹ́ẹ̀ ni, ọba Réhóbóámù dá àwọn àpáta idẹ láti fi dípò wọn, ó sì fi èyí lé àwọn alákòóso àti olùsọ́ tí ó wà ní ẹnu isẹ́ ní àbáwọlé ẹnu ọ̀nà ààfin ọba lọ́wọ́.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 12

Wo 2 Kíróníkà 12:10 ni o tọ