2 Kíróníkà 14:9 BMY

9 Ṣérà ará Kúṣì yàn láti dojú kọ wọ́n, pẹ̀lú ọ̀pọ̀ ọmọ ogun pẹ̀lú ọgọ́rùn-ún mẹ́ta kẹ̀kẹ́, wọ́n sì wá láti jìnnà réré bí Máréṣà.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 14

Wo 2 Kíróníkà 14:9 ni o tọ