11 Ní àkókò yìí, wọ́n rúbọ sí Olúwa ọgọ́rùnún méje akọ màlúù àti ẹgbẹ̀rún ḿéje (7,000) àgùntàn àti àwọn ewúrẹ́ láti ibi ìkogun tí wọ́n ti kó padà.
Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 15
Wo 2 Kíróníkà 15:11 ni o tọ