2 Kíróníkà 15:14 BMY

14 Wọ́n sì búra ní ohùn rara fún Olúwa àti pẹ̀lú ìhó nla àti pẹ̀lú ìpè àti pẹ̀lú fèrè.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 15

Wo 2 Kíróníkà 15:14 ni o tọ