2 Kíróníkà 16:9 BMY

9 Nítorí ojú Olúwa yí gbogbo ayé ká láti fi agbára fún àwọn ẹni tí ó ní ọkàn pípé sí i. Ìwọ ti ṣe ohun aṣiwèrè, láti ìsinsìnyí lọ, ìwọ yóò wà lójú ogun.”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 16

Wo 2 Kíróníkà 16:9 ni o tọ