2 Kíróníkà 17:14 BMY

14 Iye wọn gẹ́gẹ́ bí ilé baba wọn nì wọ̀nyí:Láti Júdà, àwọn olórí ìsùkan ti ẹgbẹ̀rún (1,000):Ádínà olórí, pẹ̀lú ọ̀kẹ́ mẹ́ẹ̀dó gún alágbára akọni ọkùrin (300, 00);

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 17

Wo 2 Kíróníkà 17:14 ni o tọ