2 Kíróníkà 17:7 BMY

7 Ní ọdún kẹta ìjọba rẹ̀, ó rán àwọn ìjòyè rẹ̀ Bẹni-Háílì, Obádíà Sekaríà, Nètaníélì Míkíà láti máa kọ́ ni nínú ìlú Júdà.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 17

Wo 2 Kíróníkà 17:7 ni o tọ