2 Kíróníkà 18:26 BMY

26 Ó sì wí pé ‘Èyí ni ohun tí ọba sọ: ẹ fi ènìyàn yìí sínú túbú kí ẹ má sì ṣe fún-un ní ohunkóhun ṣùgbọ́n àkàrà àti omi títí tí èmi yóò fi dé ní àlàáfíà.’ ”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 18

Wo 2 Kíróníkà 18:26 ni o tọ