2 Kíróníkà 18:32 BMY

32 Ó sì ṣe, nígbà tí olórí kẹ̀kẹ́ ríi wí pé kì í ṣe ọba Ísírẹ́lì, wọ́n sì dáwọ́ lílé rẹ̀ dúró.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 18

Wo 2 Kíróníkà 18:32 ni o tọ