2 Kíróníkà 19:2 BMY

2 Jéhù aríran, ọmọ Hánánì jáde lọ láti lọ pàdé rẹ̀, ó sì wí fún ọba pé, “Sé ìwọ yóò máa ran ènìyàn búburú lọ́wọ́, kí o sì fẹ́ràn àwọn tí ó kórìíra Olúwa? Nítorí èyí, ìbínú Olúwa wà lórí wa.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 19

Wo 2 Kíróníkà 19:2 ni o tọ