2 Kíróníkà 19:4 BMY

4 Jéhóṣáfátì sì ń gbé ní Jérúsálẹ́mù ó sì jáde lọ padà láàárin àwọn ènìyàn láti Béríṣébà dé òkè ìlú Éfúráímù, ó sì mú wọn padà sọ́dọ̀ Olúwa Ọlọ́run baba wọn.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 19

Wo 2 Kíróníkà 19:4 ni o tọ