2 Kíróníkà 2:5 BMY

5 “Ilé Olúwa tí èmi yóò kọ́ yóò tóbi, nítorí pé Ọlọ́run wa tóbi ju gbogbo àwọn Ọlọ́run mìíràn lọ.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 2

Wo 2 Kíróníkà 2:5 ni o tọ