2 Kíróníkà 20:14 BMY

14 Nígbà náà, ẹ̀mí Olúwa sì bà lé Jáhásíẹ̀lì ọmọ Sékáríà, ọmọ Bénáyà, ọmọ Jéíèlì, ọmọ Mátaníyà ọmọ Léfì àti ọmọ Ásáfù, gẹ́gẹ́ bí ó ṣe dìde dúró láàrin àpèjọ ènìyàn.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 20

Wo 2 Kíróníkà 20:14 ni o tọ