2 Kíróníkà 20:18 BMY

18 Jóhóṣáfátì tẹ orí rẹ̀ ba sílẹ̀ pẹ̀lú ojú rẹ̀, àti gbogbo àwọn ènìyàn Júdà àti Jérúsálẹ́mù wólẹ̀ níwájú láti sin Olúwa.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 20

Wo 2 Kíróníkà 20:18 ni o tọ