2 Kíróníkà 20:36 BMY

36 Ó sì gbà pẹ̀lú rẹ̀ láti kan okọ̀ láti lọ sí Táríṣísì, lẹ́yìn èyí wọ́n kan ọkọ̀ ní Ésíonì-Gébérì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 20

Wo 2 Kíróníkà 20:36 ni o tọ