2 Kíróníkà 20:4 BMY

4 Àwọn ènìyàn Júdà sì kó ara wọn jọpọ̀ láti wá ìrànlọ́wọ́ láti ọ̀dọ̀ Olúwa; pẹ̀lúpẹ̀lú, wọ́n wá láti gbogbo ìlú ní Júdà láti wá a.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 20

Wo 2 Kíróníkà 20:4 ni o tọ