2 Kíróníkà 21:11 BMY

11 Òun pẹ̀lú ti kọ́ àwọn ibi gíga lórí àwọn òkè Júdà. Ó sì ti fà á kí àwọn ènìyàn Jérúsálẹ́mù ó se àgbérè pẹ̀lú ara wọn. Ó sì ti jẹ́ kí wọn ó ṣáko lọ.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 21

Wo 2 Kíróníkà 21:11 ni o tọ