2 Kíróníkà 21:14 BMY

14 Bẹ́ẹ̀ ni nísinsìn yìí, Ọlọ́run ti fẹ́rẹ́ lu àwọn ènìyàn rẹ, àwọn ọmọ rẹ, àwọn ìyàwó rẹ àti gbogbo ohun tí ó jẹ́ tìrẹ, pẹ̀lú àjàkálẹ̀-àrùn ńlá.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 21

Wo 2 Kíróníkà 21:14 ni o tọ