2 Kíróníkà 21:2 BMY

2 Àwọn ará kùnrin Jéhóramù ọmọ Jéhóṣáfatì jẹ́ Áṣáríyà, Jèhíeli, Ṣekárià. Ásáríyàhù, Míkáélí àti Ṣefátíá. Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Jéhóṣafátì ọba Ìsírẹlì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 21

Wo 2 Kíróníkà 21:2 ni o tọ