2 Kíróníkà 22:5 BMY

5 Ó tẹ̀lé ìgbìmọ̀ wọn nígbà tí ó lọ pẹ̀lú Jórámì ọmọ Áhábù ọba Ísírẹ́lì láti gbógun ti Háṣáélì ọba Árámì ní Rámótì Gílíádì. Àwọn ará Árámì ṣá Jórámì lọ́gbẹ́;

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 22

Wo 2 Kíróníkà 22:5 ni o tọ