2 Kíróníkà 23:10 BMY

10 Ó mú gbogbo àwọn ọkùnrin wà ní ipò ìdúró pẹ̀lú ohun ìjà rẹ̀ ní ọwọ́ rẹ̀, yí ọba ká ní ẹ̀bá pẹpẹ àti ilé Olúwa láti ìhà gúsù sí ìhà àríwa ilé Olúwa.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 23

Wo 2 Kíróníkà 23:10 ni o tọ