2 Kíróníkà 23:14 BMY

14 Jéhóiádà àlùfáà mú àwọn alákóso ọrọrún, tí ó wà ní àbojútó àwọn ọ̀wọ́ ogun, ó sì wá wí fún wọn pé: “Mú un jáde wá láàrin àwọn ọgbà, kí ẹ sì pa ẹnikẹ́ni tí ó bá tẹ̀le.” Nítorí tí àlùfáà ti wí pé, “Má se paá nínú ilé Olúwa.”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 23

Wo 2 Kíróníkà 23:14 ni o tọ