2 Kíróníkà 23:2 BMY

2 Wọ́n lọ sí gbogbo Júdà, wọ́n sì pe àwọn ará Léfì àti àwọn olórí àwọn ìdílé àwọn ará Ísírẹ́lì láti gbogbo àwọn ìlú jọ. Nígbà tí wọ́n wá sí Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 23

Wo 2 Kíróníkà 23:2 ni o tọ