2 Kíróníkà 24:1 BMY

1 Jóásì jẹ́ ọmọ ọdún méje nígbà tí ó jẹ ọba, ó sì jọba ní Jérúsálẹ́mù fún ogójì ọdún. Orúkọ ìya rẹ̀ ni Ṣíbíà ti Béríṣébà.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 24

Wo 2 Kíróníkà 24:1 ni o tọ