15 Ṣùgbọ́n Jéhóiádà di arúgbó, ó sì kún fún ọjọ́, ó sì kú, ẹni àádóje ọdún ni nígbà tí ó kú.
Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 24
Wo 2 Kíróníkà 24:15 ni o tọ