2 Kíróníkà 24:18 BMY

18 Wọ́n pa ilé Olúwa tì, Ọlọ́run baba a wọn. Wọ́n sì ń sin àwọn òpó Áṣérà àti àwọn òrìṣà. Nítorí ẹbí wọn, ìbínu Ọlọ́run dé sórí Júdà àti Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 24

Wo 2 Kíróníkà 24:18 ni o tọ