2 Kíróníkà 25:20 BMY

20 Ámásíà, bí ó tì wù kí ó rí kò ní tẹ́tí nítorí Ọlọ́run ṣe é kí ó lè gbé wọn lé Jéhóásì lọ́wọ́: nítorí wọ́n wá àwọn ọlọ́run Édómù.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 25

Wo 2 Kíróníkà 25:20 ni o tọ