2 Kíróníkà 26:16 BMY

16 Ṣùgbọ́n lẹ́yìn ìgbà tí Ùsáyà jẹ́ alágbára tán, ìgbéraga rẹ̀ sì gbé e ṣubú. Ó sì di aláìsòótọ́ sí Olúwa Ọlọ́run rẹ̀. Ó sì wo ilé Olúwa láti sun tùràrí lórí pẹpẹ tùràrí.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 26

Wo 2 Kíróníkà 26:16 ni o tọ