2 Kíróníkà 26:20 BMY

20 Nígbà tí Ásáríyà olórí àlùfáà àti gbogbo àwọn àlùfáà yòókù sì wò ó, wọ́n sì ríi wí pé ó ní ẹ̀tẹ̀ níwájú orí rẹ̀, Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sì sáré gbé e jáde pẹ̀lú pẹ̀lú, òun tìkálárarẹ̀ ti fẹ́ láti jáde, nítorí tí Olúwa ti lùú.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 26

Wo 2 Kíróníkà 26:20 ni o tọ