2 Kíróníkà 26:23 BMY

23 Ùsáyà sì sùn pẹ̀lú àwọn baba, rẹ̀ a sì sin sí ẹ̀gbẹ́ wọn nínú oko ìsìnkú fún ti iṣẹ́ tí àwọn ọba, nítorí àwọn ènìyàn wí pé “ó ní àrùn ẹ̀tẹ̀,” Jótamù ọmọ rẹ̀ sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 26

Wo 2 Kíróníkà 26:23 ni o tọ