2 Kíróníkà 26:5 BMY

5 Ó sì wá Olúwa ní ọjọ́ Sekaríà, ẹni tí ó ní òye nínú ìran Ọlọ́run. Níwọ̀n ọjọ́ tí ó wá ojú Olúwa, Ọlọ́run fún-un ní ohun rere.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 26

Wo 2 Kíróníkà 26:5 ni o tọ