2 Kíróníkà 27:9 BMY

9 Jótamù sì sùn pẹ̀lú àwọn baba a rẹ̀ a sì sin ín ní ìlú Dáfídì, Áhásì ọmọ rẹ̀ sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 27

Wo 2 Kíróníkà 27:9 ni o tọ